Test
YORUBA EXAM SS 3
By Museco · All grades · Published Nov 20, 2026 · New
YORUBA EXAM SS 3
30 questions · 30 points
Question 1 · One correct answer · 1 point
Ewo ninu awon oro oruko isale yii nla seda lati ara gbolohun- A. Aya Oba
- B. Kolekole
- C. Ajewole
- D. Ayo
Question 2 · One correct answer · 1 point
Iwa omoluabi ni iwon yi aya fi- A. ikini
- B. iteriba
- C. suuru
- D. ija
Question 3 · One correct answer · 1 point
'Buredi' je oro ayalo ti a ya lati inu ede- A. Geesi
- B. Hausa
- C. Larubawa
- D. Tapa
Question 4 · One correct answer · 1 point
Oro ti aya lati ipase ilana afojuya ni- A. Baibu
- B. Telo
- C. Esiteri
- D. Tebu
Question 5 · One correct answer · 1 point
A ya 'alubarika' lati inu ede _______- A. Hausa
- B. Geesi
- C. Larubawa
- D. Togo
Question 6 · One correct answer · 1 point
Orisi ona ________ ni ogun jija pin si- A. Meta
- B. Merin
- C. Eyokan
- D. Meji
Question 7 · One correct answer · 1 point
Leta aigbefe maa n ni adiresi _______- A. Meta
- B. Merin
- C. Meji
- D. Eyokan
Question 8 · One correct answer · 1 point
Irufe eni ti a le ko leta aigbafe si ni- A. Ore
- B. baba
- C. Giwa ile ise
- D. aburo
Question 9 · One correct answer · 1 point
Igbese keji ninu leta aigbefe ni- A. Adiresi
- B. Ara leta
- C. Ikini ibere
- D. Akole leta
Question 10 · One correct answer · 1 point
Apeere gbolohun alakanpo ni- A. Yemi ke sugbon n ko gbo
- B. Ige je eba
- C. oluko ra oko
- D. aduke sun
Question 11 · One correct answer · 1 point
Orisii ogun jija melo lo wa?- A. Meta
- B. Merin
- C. Mefa
- D. Meji
Question 12 · One correct answer · 1 point
Okan lara awon wonyi kosi lara ohun ti n maa n fa ogun jija- A. ote
- B. ilara
- C. ija ile
- D. ibadoree
Question 13 · One correct answer · 1 point
Awon tii maa jagun ni aye atijo ni iwonyi ayafi- A. awon oloogun
- B. awon ipanle tabi janduku
- C. awon oba ilu
- D. awon ogboju ode
Question 14 · One correct answer · 1 point
Ewo ni ko si lara ohun ija ogun ni aye atijo- A. oko
- B. ida
- C. ofa
- D. bombu
Question 15 · One correct answer · 1 point
________ ni afo ti o kun, ti o si ni ise ton se nibikibi ti won ba ti je jade- A. konsonanti
- B. gbolohun
- C. leta
- D. silebu
Question 16 · One correct answer · 1 point
Gbolohun ti kii ni ju oro ise kan lo ni gbolohun- A. olopo oro ise
- B. alakanpo
- C. onibo
- D. eleyo oro ise
Question 17 · One correct answer · 1 point
Ihun gbolohun abode to je oluwa, oro ise kan ati oro aponle ni _________- A. ige je eba
- B. jade
- C. ile ga gogoro
- D. ojo da ile si odo
Question 18 · One correct answer · 1 point
Gbolohun ti a fi oro asopo kan po mo ara won ni gbolohun _________- A. abode
- B. eleyo oro ise
- C. alakanpo
- D. asaponle
Question 19 · One correct answer · 1 point
Apeere oro asopo ni iwonyi ayafi- A. sugbon
- B. ati
- C. olu
- D. oun
Question 20 · One correct answer · 1 point
Lara aleebu ogun jija ni- A. biba nnkan ini je
- B. a maa je ki awon eniyan di alagbara
- C. a maa fi alagbara ilu han
- D. a maa so awon alagbara di olowo ojiji
Question 21 · One correct answer · 1 point
Okan ninu awon wonyi ko si lara ona lati dekun ogun- A. iwa pele
- B. ibowo fun omolakeji
- C. nini emi idariji
- D. ibinu gbigbona
Question 22 · One correct answer · 1 point
_______ ni apa kan gbolohun. ole je oro tabi akojopo oro- A. awe gbolohun
- B. apola
- C. atokun
- D. gbolohun
Question 23 · One correct answer · 1 point
_______ ko le da duro ki o fun wa ni itumo kikun- A. apola
- B. awe gbolohun
- C. gbolohun abode
- D. gbolohun alakanpo
Question 24 · One correct answer · 1 point
'iwo ati emi' je apeere- A. gbolohun abode
- B. apola
- C. awe gbolohun
- D. gbolohun onibo
Question 25 · One correct answer · 1 point
'kekere' di 'kekee' nipa se _______- A. iparoje
- B. aranmo
- C. isunki
- D. isodipupo
Question 26 · One correct answer · 1 point
Iro ti a paje ninu 'iroyin' to di 'iroin' ni iro______- A. i
- B. o
- C. y
- D. in
Question 27 · One correct answer · 1 point
________ ni isodara eni ti o maa n waye ni aarin iro meji- A. ipaje
- B. isunki
- C. aranmo
- D. ohun
Question 28 · One correct answer · 1 point
Toka si apeere aranmowaju ninu awon wonyi- A. arooko
- B. iya egbe
- C. aro oke
- D. iweele
Question 29 · One correct answer · 1 point
Ewo ni apeere aranmo aforo(afo iro)- A. ileese
- B. alata
- C. kuule
- D. ileewe
Question 30 · One correct answer · 1 point
'Iya egbe' to di 'iyaeegbe' je apeere _______- A. aranmeyin
- B. aranmowaju
- C. aranmo aforo
- D. aranmo elebe
How it works with your class
- 1. Copy it to your accountOne click. Change anything you want.
- 2. Share a link or codeStudents open it on any device, no accounts needed.
- 3. See the resultsScores and every answer, checked for you.
More like this
Test
YORUBA TEST SS 3
All grades · New · Nov 18, 2026
Test
YORUBA C.A TEST SS 2
All grades · New · Nov 18, 2026
Test
YORUBA C.A TEST SS 1
All grades · New · Nov 18, 2026
Test
ENGLISH EXAM SS 1
All grades · New · Nov 19, 2026
Test
ENGLISH EXAM SS 3
All grades · New · Nov 20, 2026
Test
ENGLISH EXAM SS 2
All grades · New · Nov 20, 2026