Skip to content
Get started free

Test

YORUBA EXAM SS 3

By Museco · All grades · Published Nov 20, 2026 · New

YORUBA EXAM SS 3

30 questions · 30 points

  1. Question 1 · One correct answer · 1 point

    Ewo ninu awon oro oruko isale yii nla  seda lati ara gbolohun 
    1. A. Aya Oba
    2. B. Kolekole
    3. C. Ajewole
    4. D. Ayo
  2. Question 2 · One correct answer · 1 point

    Iwa omoluabi ni iwon yi aya fi 
    1. A. ikini
    2. B. iteriba
    3. C. suuru
    4. D. ija
  3. Question 3 · One correct answer · 1 point

    'Buredi' je oro ayalo ti a ya lati inu ede 
    1. A. Geesi
    2. B. Hausa
    3. C. Larubawa
    4. D. Tapa
  4. Question 4 · One correct answer · 1 point

    Oro ti aya lati ipase ilana afojuya ni 
    1. A. Baibu
    2. B. Telo
    3. C. Esiteri
    4. D. Tebu
  5. Question 5 · One correct answer · 1 point

    A ya 'alubarika' lati inu ede _______ 
    1. A. Hausa
    2. B. Geesi
    3. C. Larubawa
    4. D. Togo
  6. Question 6 · One correct answer · 1 point

    Orisi ona ________ ni ogun jija pin si 
    1. A. Meta
    2. B. Merin
    3. C. Eyokan
    4. D. Meji
  7. Question 7 · One correct answer · 1 point

    Leta aigbefe maa n ni adiresi _______ 
    1. A. Meta
    2. B. Merin
    3. C. Meji
    4. D. Eyokan
  8. Question 8 · One correct answer · 1 point

    Irufe eni ti a le ko leta aigbafe si ni 
    1. A. Ore
    2. B. baba
    3. C. Giwa ile ise
    4. D. aburo
  9. Question 9 · One correct answer · 1 point

    Igbese keji ninu leta aigbefe ni 
    1. A. Adiresi
    2. B. Ara leta
    3. C. Ikini ibere
    4. D. Akole leta
  10. Question 10 · One correct answer · 1 point

    Apeere gbolohun alakanpo ni 
    1. A. Yemi ke sugbon n ko gbo
    2. B. Ige je eba
    3. C. oluko ra oko
    4. D. aduke sun
  11. Question 11 · One correct answer · 1 point

    Orisii ogun jija melo lo wa? 
    1. A. Meta
    2. B. Merin
    3. C. Mefa
    4. D. Meji
  12. Question 12 · One correct answer · 1 point

    Okan lara awon wonyi kosi lara ohun ti n maa n fa ogun jija 
    1. A. ote
    2. B. ilara
    3. C. ija ile
    4. D. ibadoree
  13. Question 13 · One correct answer · 1 point

    Awon tii maa jagun ni aye atijo ni iwonyi ayafi 
    1. A. awon oloogun
    2. B. awon ipanle tabi janduku
    3. C. awon oba ilu
    4. D. awon ogboju ode
  14. Question 14 · One correct answer · 1 point

    Ewo ni ko si lara ohun ija ogun ni aye atijo 
    1. A. oko
    2. B. ida
    3. C. ofa
    4. D. bombu
  15. Question 15 · One correct answer · 1 point

    ________ ni afo ti o kun, ti o si ni ise ton se nibikibi ti won ba ti je jade 
    1. A. konsonanti
    2. B. gbolohun
    3. C. leta
    4. D. silebu
  16. Question 16 · One correct answer · 1 point

    Gbolohun ti kii ni ju oro ise kan lo ni gbolohun 
    1. A. olopo oro ise
    2. B. alakanpo
    3. C. onibo
    4. D. eleyo oro ise
  17. Question 17 · One correct answer · 1 point

    Ihun gbolohun abode to je oluwa, oro ise kan ati oro aponle ni _________ 
    1. A. ige je eba
    2. B. jade
    3. C. ile ga gogoro
    4. D. ojo da ile si odo
  18. Question 18 · One correct answer · 1 point

    Gbolohun ti a fi oro asopo kan po mo  ara won ni gbolohun _________ 
    1. A. abode
    2. B. eleyo oro ise
    3. C. alakanpo
    4. D. asaponle
  19. Question 19 · One correct answer · 1 point

    Apeere oro asopo ni iwonyi ayafi 
    1. A. sugbon
    2. B. ati
    3. C. olu
    4. D. oun
  20. Question 20 · One correct answer · 1 point

    Lara aleebu ogun jija ni 
    1. A. biba nnkan ini je
    2. B. a maa je ki awon eniyan di alagbara
    3. C. a maa fi alagbara ilu han
    4. D. a maa so awon alagbara di olowo ojiji
  21. Question 21 · One correct answer · 1 point

    Okan ninu awon wonyi ko si lara ona lati dekun ogun
    1. A. iwa pele
    2. B. ibowo fun omolakeji
    3. C. nini emi idariji
    4. D. ibinu gbigbona
  22. Question 22 · One correct answer · 1 point

    _______ ni apa kan gbolohun. ole je oro tabi akojopo oro
    1. A. awe gbolohun
    2. B. apola
    3. C. atokun
    4. D. gbolohun
  23. Question 23 · One correct answer · 1 point

    _______ ko le da duro ki o fun wa ni itumo kikun
    1. A. apola
    2. B. awe gbolohun
    3. C. gbolohun abode
    4. D. gbolohun alakanpo
  24. Question 24 · One correct answer · 1 point

    'iwo ati emi' je apeere 
    1. A. gbolohun abode
    2. B. apola
    3. C. awe gbolohun
    4. D. gbolohun onibo
  25. Question 25 · One correct answer · 1 point

    'kekere' di 'kekee' nipa se _______ 
    1. A. iparoje
    2. B. aranmo
    3. C. isunki
    4. D. isodipupo
  26. Question 26 · One correct answer · 1 point

    Iro ti a paje ninu 'iroyin' to di 'iroin' ni iro______
    1. A. i
    2. B. o
    3. C. y
    4. D. in
  27. Question 27 · One correct answer · 1 point

    ________ ni isodara eni ti o maa n waye ni aarin iro meji
    1. A. ipaje
    2. B. isunki
    3. C. aranmo
    4. D. ohun
  28. Question 28 · One correct answer · 1 point

    Toka si apeere aranmowaju ninu awon wonyi  
    1. A. arooko
    2. B. iya egbe
    3. C. aro oke
    4. D. iweele
  29. Question 29 · One correct answer · 1 point

    Ewo ni apeere aranmo aforo(afo iro)
    1. A. ileese
    2. B. alata
    3. C. kuule
    4. D. ileewe
  30. Question 30 · One correct answer · 1 point

    'Iya egbe' to di 'iyaeegbe' je apeere _______ 
    1. A. aranmeyin
    2. B. aranmowaju
    3. C. aranmo aforo
    4. D. aranmo elebe

How it works with your class

  1. 1. Copy it to your accountOne click. Change anything you want.
  2. 2. Share a link or codeStudents open it on any device, no accounts needed.
  3. 3. See the resultsScores and every answer, checked for you.
Sign up free

More like this