Test
YORUBA C.A TEST SS 2
By Museco · All grades · Published Nov 18, 2026 · New
YORUBA C.A TEST SS 2
10 questions · 10 points
Question 1 · One correct answer · 1 point
Ami ohun isale ni o wa ni ori- A. titi
- B. Dodo
- C. Ileri
- D. ori
Question 2 · One correct answer · 1 point
______________ni eto amulo iro ede kookan- A. foniimu
- B. Faweli
- C. fonoloji
- D. silebu
Question 3 · One correct answer · 1 point
Osuwon ti o n fi iyato han laarin iro kan si ekeji ni- A. faweli
- B. silebu
- C. foniimu
- D. fonologi
Question 4 · One correct answer · 1 point
Akojopo oro tio kun fun ogbon ,imo ijinle ati iriri awon agba- A. akanlo
- B. owe
- C. ona ede
- D. faweli
Question 5 · One correct answer · 1 point
Apeere owe fun imoran ni- A. Alagemo ti bimo ,aimoojo ku sowo omo alagemo
- B. Afase gbe ojo o n tan ara re je
- C. Ki ile to pa osika,ohun rere a ti baje
- D. Agboju logun fi ara re fun osi ta
Question 6 · One correct answer · 1 point
Oro ti o maa n saaju oro oruko ti o je abo ninu gbolohun ni oro- A. atokun
- B. asopo
- C. aponle
- D. apejuwe
Question 7 · One correct answer · 1 point
Toka si oro atokun inu gbolohun yii ''Olubisi ti Eko de''- A. Olubisi
- B. Eko
- C. ti
- D. de
Question 8 · One correct answer · 1 point
Oro ti a fi n so awon oro po ni oro- A. apejuwe
- B. oruko
- C. asopo
- D. atokun
Question 9 · One correct answer · 1 point
Apeere oro asopo ni iwonyi AYAFI- A. ati
- B. pelu
- C. oun
- D. olu
Question 10 · One correct answer · 1 point
''Ade ati Sola lo wa'' Oro asopo inu gbolo- A. Ade
- B. ati
- C. Sola
- D. lo wa
How it works with your class
- 1. Copy it to your accountOne click. Change anything you want.
- 2. Share a link or codeStudents open it on any device, no accounts needed.
- 3. See the resultsScores and every answer, checked for you.
More like this
Test
YORUBA C.A TEST SS 1
All grades · New · Nov 18, 2026
Test
YORUBA TEST SS 3
All grades · New · Nov 18, 2026
Test
YORUBA EXAM SS 3
All grades · New · Nov 20, 2026
Test
ENGLISH EXAM SS 1
All grades · New · Nov 19, 2026
Test
ENGLISH EXAM SS 3
All grades · New · Nov 20, 2026
Test
ENGLISH EXAM SS 2
All grades · New · Nov 20, 2026